ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • g17 No. 6 ojú ìwé 16
  • Atọ́ka Àwọn Àkòrí fún Jí! 2017

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Atọ́ka Àwọn Àkòrí fún Jí! 2017
  • Jí!—2017
  • Ìsọ̀rí
  • ÀWỌN ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ
  • ÀWỌN ẸNI INÚ ÌTÀN
  • ÀWỌN ẸRANKO ÀTI EWÉKO
  • Ẹ̀SÌN
  • ÌFỌ̀RỌ̀WÁNILẸ́NUWÒ
  • ÌLERA ÀTI ÌTỌ́JÚ
  • ILẸ̀ ÀTI ÀWỌN ÈÈYÀN
  • OHUN TÓ Ń LỌ LÁYÉ
  • OJÚ ÌWÒYE BÍBÉLÌ
  • Ọ̀KAN-Ò-JỌ̀KAN
  • SÁYẸ́ǸS
Jí!—2017
g17 No. 6 ojú ìwé 16

Atọ́ka Àwọn Àkòrí fún Jí! 2017

Jí! ni ìwé ìròyìn tó dá lórí oríṣiríṣi nǹkan tó sì délé-dóko jù lọ láyé!

Ó lé ní 360 mílíọ̀nù ẹ̀dà tá à ń tẹ̀ ní ohun tó ju ọgọ́rùn-ún èdè lọ!

ÀJỌṢE ÀWỌN ÈÈYÀN

  • Bó O Ṣe Lè Kọ́ Ọmọ Rẹ Ní Ẹ̀mí Ìrẹ̀lẹ̀ (ọmọ títọ́): No. 6

  • Bó O Ṣe Lè Mọyì Ẹnì Kejì Rẹ (ìgbéyàwó): No. 1

  • Ẹ̀rín Músẹ́​—Ẹ̀bùn Tó O Lè Fúnni: No. 1

  • Iṣẹ́ Ilé Ṣe Pàtàkì (ọmọ títọ́), No. 3

  • Kí Làwọn Èèyàn Ń Rí Nínú Eré Tó Léwu? (àwọn ọ̀dọ́): No. 5

  • Nígbà Tí Àwọn Ọmọ Bá Ti Kúrò Nílé (ìgbéyàwó): No. 4

  • Nígbà Tí Òbí Ẹnì Kan Bá Kú (àwọn ọ̀dọ́): No. 2

  • ‘Orúkọ Rere Dára Ju Ọ̀pọ̀ Yanturu Ọrọ̀ Lọ’: No. 4

  • Tí Òbí Ọmọdé Kan Bá Kú: No. 2

ÀWỌN ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ

  • “Irú Ìfẹ́ Yìí Wú Wa Lórí Gan-an Ni” (ìmìtìtì ilẹ̀ lórílẹ̀-èdè Nepal): No. 1

ÀWỌN ẸNI INÚ ÌTÀN

  • Alhazen: No. 6

ÀWỌN ẸRANKO ÀTI EWÉKO

  • Ẹyẹ Arctic Tern: No. 4

Ẹ̀SÌN

  • Ṣé Ọ̀dọ̀ Ọlọ́run Ni Bíbélì Ti Wá Lóòótọ́? No. 3

ÌFỌ̀RỌ̀WÁNILẸ́NUWÒ

  • Onímọ̀ Nípa Àrùn Ọpọlọ Ṣàlàyé Ohun Tó Gbà Gbọ́ (Rajesh Kalaria): No. 4

  • Onímọ̀ Nípa Ètò Orí Kọ̀ǹpútà Ṣàlàyé Ohun Tó Gbà Gbọ́ (Dr. Fan Yu): No. 3

ÌLERA ÀTI ÌTỌ́JÚ

  • Àwọn Ọ̀dọ́ Tó Ní Ìdààmú Ọkàn: No. 1

ILẸ̀ ÀTI ÀWỌN ÈÈYÀN

  • Kazakhstan: No. 5

  • New Zealand: No. 6

  • Sípéènì: No. 2

OHUN TÓ Ń LỌ LÁYÉ

  • Ṣé Ayé Yìí Ti Bà Jẹ́ Kọjá Àtúnṣe? No. 6

  • Tí Àjálù Bá Ṣẹlẹ̀​​—Ohun Tó O Lè Ṣe Láti Gbẹ̀mí Là: No. 5

OJÚ ÌWÒYE BÍBÉLÌ

  • Àgbélébùú: No. 2

  • Áńgẹ́lì: No. 3

  • Ìdẹwò: No. 4

  • Ìṣẹ́yún: No. 1

  • Ogun: No. 5

  • Orúkọ Ọlọ́run: No. 6

Ọ̀KAN-Ò-JỌ̀KAN

  • Bó O Ṣe Lè Máa Ṣọ́ Nǹkan Lò: No. 5

  • Ohun Tó Yẹ Kó O Mọ̀ Nípa Agbára Abàmì No. 2

  • Ṣé Ọwọ́ Rẹ Máa Ń Dí Jù? No. 4

SÁYẸ́ǸS

  • Èso Pollia: No. 4

  • Ìkarawun Ìṣáwùrú: No. 5

  • Irun Ara Ẹran Omi Tó Ń Jẹ́ Otter: No. 3

  • Ìṣùpọ̀ Iṣan Enteric Nervous System: No. 3

  • Kòkòrò Saharan Silver: No. 1

  • Ọgbọ́n Tí Oyin Fi Ń Bà Lé Nǹkan: No. 2

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́