ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • w23 June ojú ìwé 32
  • Àwọn Àpilẹ̀kọ Míì Nínú “Ilé Ìṣọ́”

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Àwọn Àpilẹ̀kọ Míì Nínú “Ilé Ìṣọ́”
  • Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2023
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Bó O Ṣe Lè Lo Ìkànnì Wa
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2023
  • Ilé Ìṣọ́ Ẹ̀dà Tuntun Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2008
  • Ohun Tó O Lè Fi Kẹ́kọ̀ọ́
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2023
  • Wàá Rí Ìmọ̀ràn Tó Máa Ràn Ẹ́ Lọ́wọ́ Lórí Ìkànnì JW.ORG
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
Àwọn Míì
Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2023
w23 June ojú ìwé 32

Àwọn Àpilẹ̀kọ Míì Nínú Ilé Ìṣọ́

Ọ̀pọ̀ àwọn ará ló máa ń lo JW Library® láti múra ìpàdé sílẹ̀, wọ́n sì máa ń mọyì bó ṣe máa ń gbé wọn lọ sí àpilẹ̀kọ Ilé Ìṣọ́ kọ̀ọ̀kan tá a máa kẹ́kọ̀ọ́. Àmọ́ Ilé Ìṣọ́ tá à ń lò fún ìkẹ́kọ̀ọ́ tún máa ń ní àwọn àpilẹ̀kọ míì tá a lè kẹ́kọ̀ọ́ nínú ẹ̀ àmọ́ tá à kì í kà nípàdé. Torí náà, báwo lo ṣe lè rí àwọn àpilẹ̀kọ yìí lórí JW Library, kó o sì jàǹfààní nínú ẹ̀?

  • Ní ìsàlẹ̀ àpilẹ̀kọ Ilé Ìṣọ́ kọ̀ọ̀kan tá a máa kẹ́kọ̀ọ́, a máa rí “Àfikún.” Lábẹ́ àfikún yẹn, tẹ “Àwọn àpilẹ̀kọ míì nínú ìtẹ̀jáde yìí.” Wo àwọn àkòrí tó wà nínú ìwé yẹn àtàwọn nọ́ńbà àpilẹ̀kọ náà. Lẹ́yìn náà, tẹ àwọn àpilẹ̀kọ míì tó o fẹ́ kà nínú Ilé Ìṣọ́ yẹn.

  • Tó o bá ti wà ní Ojú Ìwé Àkọ́kọ́ lórí JW Library, lọ sí “Ohun Tuntun” kó o sì wa Ilé Ìṣọ́ tuntun tó bá wà níbẹ̀ jáde. Lẹ́yìn náà, ṣí Ilé Ìṣọ́ tó o wà jáde, lọ sí apá ohun tó wà nínú ìwé yìí kó o lè jàǹfààní nínú gbogbo àpilẹ̀kọ tó wà níbẹ̀.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́