Lúùkù 17:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 wọ́n ń jẹ, wọ́n ń mu, àwọn ọkùnrin ń gbéyàwó, à ń fa àwọn obìnrin fún ọkọ, títí di ọjọ́ tí Nóà wọ ọkọ̀ áàkì,+ Ìkún Omi sì dé, ó pa gbogbo wọn run.+ Hébérù 11:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ìgbàgbọ́ mú kí Nóà + fi ìbẹ̀rù Ọlọ́run hàn, lẹ́yìn tó gba ìkìlọ̀ láti ọ̀run nípa àwọn ohun tí a kò tíì rí,+ ó kan ọkọ̀ áàkì+ kí agbo ilé rẹ̀ lè rí ìgbàlà; ó dá ayé lẹ́bi nípasẹ̀ ìgbàgbọ́ yìí,+ ó sì di ajogún òdodo irú èyí tí ìgbàgbọ́ ń mú wá.
27 wọ́n ń jẹ, wọ́n ń mu, àwọn ọkùnrin ń gbéyàwó, à ń fa àwọn obìnrin fún ọkọ, títí di ọjọ́ tí Nóà wọ ọkọ̀ áàkì,+ Ìkún Omi sì dé, ó pa gbogbo wọn run.+
7 Ìgbàgbọ́ mú kí Nóà + fi ìbẹ̀rù Ọlọ́run hàn, lẹ́yìn tó gba ìkìlọ̀ láti ọ̀run nípa àwọn ohun tí a kò tíì rí,+ ó kan ọkọ̀ áàkì+ kí agbo ilé rẹ̀ lè rí ìgbàlà; ó dá ayé lẹ́bi nípasẹ̀ ìgbàgbọ́ yìí,+ ó sì di ajogún òdodo irú èyí tí ìgbàgbọ́ ń mú wá.