ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Léfítíkù 7:29-31
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 29 “Sọ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé, ‘Kí ẹnikẹ́ni tó bá fẹ́ mú ẹbọ ìrẹ́pọ̀ wá fún Jèhófà mú ọrẹ wá fún Jèhófà látinú ẹbọ ìrẹ́pọ̀ rẹ̀.+ 30 Ọwọ́ ara rẹ̀ ni kó fi mú ọ̀rá+ pẹ̀lú igẹ̀ wá láti fi ṣe ọrẹ àfinásun sí Jèhófà, kó sì fì í síwá-sẹ́yìn bí ọrẹ fífì+ níwájú Jèhófà. 31 Kí àlùfáà mú kí ọ̀rá náà rú èéfín lórí pẹpẹ,+ àmọ́ igẹ̀ náà jẹ́ ti Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́