Léfítíkù 23:27, 28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 “Ọjọ́ kẹwàá oṣù keje yìí ni Ọjọ́ Ètùtù.+ Kí ẹ ṣe àpéjọ mímọ́, kí ẹ pọ́n ara yín* lójú,+ kí ẹ sì ṣe ọrẹ àfinásun sí Jèhófà. 28 Ẹ má ṣe iṣẹ́ kankan ní ọjọ́ yìí gangan, torí ó jẹ́ ọjọ́ ètùtù tí wọ́n á ṣe ètùtù+ fún yín níwájú Jèhófà Ọlọ́run yín. Nọ́ńbà 29:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 “‘Kí ẹ ṣe àpéjọ mímọ́+ ní ọjọ́ kẹwàá oṣù keje yìí, kí ẹ sì pọ́n ara yín* lójú. Ẹ kò gbọ́dọ̀ ṣe iṣẹ́ kankan.+
27 “Ọjọ́ kẹwàá oṣù keje yìí ni Ọjọ́ Ètùtù.+ Kí ẹ ṣe àpéjọ mímọ́, kí ẹ pọ́n ara yín* lójú,+ kí ẹ sì ṣe ọrẹ àfinásun sí Jèhófà. 28 Ẹ má ṣe iṣẹ́ kankan ní ọjọ́ yìí gangan, torí ó jẹ́ ọjọ́ ètùtù tí wọ́n á ṣe ètùtù+ fún yín níwájú Jèhófà Ọlọ́run yín.
7 “‘Kí ẹ ṣe àpéjọ mímọ́+ ní ọjọ́ kẹwàá oṣù keje yìí, kí ẹ sì pọ́n ara yín* lójú. Ẹ kò gbọ́dọ̀ ṣe iṣẹ́ kankan.+