Diutarónómì 31:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Àwọn ọmọ wọn tí kò tíì mọ Òfin yìí á wá fetí sílẹ̀,+ wọ́n á sì kọ́ láti máa bẹ̀rù Jèhófà Ọlọ́run yín ní gbogbo ọjọ́ tí ẹ bá fi wà lórí ilẹ̀ tí ẹ̀ ń sọdá Jọ́dánì lọ gbà.”+ Sáàmù 78:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Kí ìran tó ń bọ̀,Ìyẹn àwọn ọmọ tí wọ́n máa bí, lè mọ̀ wọ́n.+ Kí àwọn náà lè ròyìn wọn fún àwọn ọmọ wọn.+
13 Àwọn ọmọ wọn tí kò tíì mọ Òfin yìí á wá fetí sílẹ̀,+ wọ́n á sì kọ́ láti máa bẹ̀rù Jèhófà Ọlọ́run yín ní gbogbo ọjọ́ tí ẹ bá fi wà lórí ilẹ̀ tí ẹ̀ ń sọdá Jọ́dánì lọ gbà.”+
6 Kí ìran tó ń bọ̀,Ìyẹn àwọn ọmọ tí wọ́n máa bí, lè mọ̀ wọ́n.+ Kí àwọn náà lè ròyìn wọn fún àwọn ọmọ wọn.+