Ẹ́kísódù 13:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 “Ya gbogbo àkọ́bí ọkùnrin* nínú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sí mímọ́* fún mi. Tèmi ni àkọ́bí yín lọ́kùnrin àti àkọ́bí ẹran yín tó jẹ́ akọ.”+ Ẹ́kísódù 34:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 “Tèmi ni gbogbo ọmọkùnrin tó jẹ́ àkọ́bí,*+ pẹ̀lú gbogbo ẹran ọ̀sìn yín, yálà ó jẹ́ àkọ́bí akọ màlúù tàbí ti àgùntàn.+ Nọ́ńbà 18:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 “Àkọ́bí gbogbo ohun alààyè,*+ tí wọ́n bá mú wá fún Jèhófà, ì báà jẹ́ èèyàn tàbí ẹranko, yóò di tìrẹ. Àmọ́, o gbọ́dọ̀ ra àkọ́bí èèyàn+ pa dà, kí o sì tún ra àkọ́bí àwọn ẹran tó jẹ́ aláìmọ́ pa dà.+ Lúùkù 2:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 bí a ṣe kọ ọ́ sínú Òfin Jèhófà* pé: “Gbogbo àkọ́bí ọkùnrin* ni ká pè ní mímọ́ fún Jèhófà.”*+
2 “Ya gbogbo àkọ́bí ọkùnrin* nínú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sí mímọ́* fún mi. Tèmi ni àkọ́bí yín lọ́kùnrin àti àkọ́bí ẹran yín tó jẹ́ akọ.”+
19 “Tèmi ni gbogbo ọmọkùnrin tó jẹ́ àkọ́bí,*+ pẹ̀lú gbogbo ẹran ọ̀sìn yín, yálà ó jẹ́ àkọ́bí akọ màlúù tàbí ti àgùntàn.+
15 “Àkọ́bí gbogbo ohun alààyè,*+ tí wọ́n bá mú wá fún Jèhófà, ì báà jẹ́ èèyàn tàbí ẹranko, yóò di tìrẹ. Àmọ́, o gbọ́dọ̀ ra àkọ́bí èèyàn+ pa dà, kí o sì tún ra àkọ́bí àwọn ẹran tó jẹ́ aláìmọ́ pa dà.+