ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Nọ́ńbà 14:35
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 35 “‘“Èmi Jèhófà ti sọ̀rọ̀. Ohun tí màá ṣe fún àwọn èèyàn burúkú yìí tí wọ́n kóra jọ láti ta kò mí nìyí: Inú aginjù yìí ni wọ́n máa ṣègbé sí, ibí ni wọ́n sì máa kú sí.+

  • Nọ́ńbà 16:1, 2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 Kórà+ ọmọ Ísárì,+ ọmọ Kóhátì,+ ọmọ Léfì+ wá gbìmọ̀ pọ̀ pẹ̀lú Dátánì àti Ábírámù, àwọn ọmọ Élíábù+ pẹ̀lú Ónì ọmọ Péléétì, àwọn ọmọ Rúbẹ́nì.+ 2 Wọ́n dìtẹ̀ Mósè, àwọn àti igba ó lé àádọ́ta (250) ọkùnrin tó jẹ́ ọmọ Ísírẹ́lì, àwọn ìjòyè àpéjọ náà, àwọn tí a yàn nínú ìjọ, àwọn ọkùnrin tó lókìkí.

  • Nọ́ńbà 16:19
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 19 Nígbà tí Kórà kó àwọn tó ń tì í lẹ́yìn,+ tí wọ́n jọ ń ta kò wọ́n jọ sí ẹnu ọ̀nà àgọ́ ìpàdé, ògo Jèhófà fara han gbogbo àpéjọ+ náà.

  • Nọ́ńbà 16:35
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 35 Iná sì wá látọ̀dọ̀ Jèhófà,+ ó jó igba ó lé àádọ́ta (250) ọkùnrin tó ń sun tùràrí+ run.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́