-
Nọ́ńbà 18:15, 16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 “Àkọ́bí gbogbo ohun alààyè,*+ tí wọ́n bá mú wá fún Jèhófà, ì báà jẹ́ èèyàn tàbí ẹranko, yóò di tìrẹ. Àmọ́, o gbọ́dọ̀ ra àkọ́bí èèyàn+ pa dà, kí o sì tún ra àkọ́bí àwọn ẹran tó jẹ́ aláìmọ́ pa dà.+ 16 Tó bá ti pé oṣù kan tàbí jù bẹ́ẹ̀ lọ, kí o san owó ìràpadà láti rà á pa dà, kí o san ṣékélì*+ fàdákà márùn-ún tí wọ́n dá lé e, kó jẹ́ ìwọ̀n ṣékélì ibi mímọ́.* Ó jẹ́ ogún (20) òṣùwọ̀n gérà.*
-