-
1 Kíróníkà 15:24Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
24 Àwọn àlùfáà, ìyẹn Ṣebanáyà, Jóṣáfátì, Nétánélì, Ámásáì, Sekaráyà, Bẹnáyà àti Élíésérì ń fun kàkàkí kíkankíkan níwájú Àpótí Ọlọ́run tòótọ́,+ Obedi-édómù àti Jeháyà sì ni aṣọ́bodè tó ń ṣọ́ Àpótí.
-
-
1 Kíróníkà 16:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Bẹnáyà àti Jáhásíẹ́lì tí wọ́n jẹ́ àlùfáà sì ń fun kàkàkí déédéé níwájú àpótí májẹ̀mú Ọlọ́run tòótọ́.
-
-
2 Kíróníkà 29:26Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
26 Nítorí náà, àwọn ọmọ Léfì dúró pẹ̀lú àwọn ohun ìkọrin Dáfídì lọ́wọ́, àwọn àlùfáà sì dúró pẹ̀lú kàkàkí lọ́wọ́.+
-
-
Nehemáyà 12:41Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
41 àti àwọn àlùfáà, ìyẹn Élíákímù, Maaseáyà, Míníámínì, Mikáyà, Élíóénáì, Sekaráyà àti Hananáyà pẹ̀lú àwọn kàkàkí lọ́wọ́
-