Nọ́ńbà 11:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Jóṣúà+ ọmọ Núnì tó jẹ́ ìránṣẹ́ Mósè láti kékeré fèsì pé: “Mósè olúwa mi, pa wọ́n lẹ́nu mọ́!”+ Nọ́ńbà 13:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Èyí ni orúkọ àwọn ọkùnrin tí Mósè rán láti ṣe amí ilẹ̀ náà. Mósè wá sọ Hóṣéà ọmọ Núnì ní Jóṣúà.*+ Nọ́ńbà 14:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Ìkankan nínú yín kò ní wọ ilẹ̀ tí mo búra* pé ẹ máa gbé,+ àfi Kélẹ́bù ọmọ Jéfúnè àti Jóṣúà ọmọ Núnì.+ Nọ́ńbà 34:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Orúkọ àwọn ọkùnrin tó máa pín ilẹ̀ tí yóò di tiyín fún yín nìyí: àlùfáà Élíásárì+ àti Jóṣúà+ ọmọ Núnì.
30 Ìkankan nínú yín kò ní wọ ilẹ̀ tí mo búra* pé ẹ máa gbé,+ àfi Kélẹ́bù ọmọ Jéfúnè àti Jóṣúà ọmọ Núnì.+
17 Orúkọ àwọn ọkùnrin tó máa pín ilẹ̀ tí yóò di tiyín fún yín nìyí: àlùfáà Élíásárì+ àti Jóṣúà+ ọmọ Núnì.