-
Léfítíkù 6:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 “‘Òfin ọrẹ ọkà+ nìyí: Kí ẹ̀yin ọmọ Áárónì mú un wá síwájú Jèhófà, ní iwájú pẹpẹ.
-
-
Nọ́ńbà 28:11, 12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 “‘Ní ìbẹ̀rẹ̀ oṣù kọ̀ọ̀kan,* kí ẹ mú akọ ọmọ màlúù méjì, àgbò kan àti akọ ọ̀dọ́ àgùntàn méje tí ara wọn dá ṣáṣá tí ọ̀kọ̀ọ̀kan jẹ́ ọlọ́dún kan+ wá láti fi rú ẹbọ sísun sí Jèhófà, 12 pẹ̀lú ìyẹ̀fun kíkúnná tó jẹ́ ìdá mẹ́ta nínú mẹ́wàá òṣùwọ̀n tí wọ́n pò mọ́ òróró láti fi ṣe ọrẹ ọkà + fún akọ màlúù kọ̀ọ̀kan àti ìyẹ̀fun kíkúnná tó jẹ́ ìdá méjì nínú mẹ́wàá òṣùwọ̀n tí wọ́n pò mọ́ òróró láti fi ṣe ọrẹ ọkà fún àgbò+ náà,
-