Jẹ́nẹ́sísì 36:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ísọ̀ wá ń gbé ní agbègbè olókè Séírì.+ Ísọ̀ ni Édómù.+ Diutarónómì 2:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Kí o sì pàṣẹ fún àwọn èèyàn náà pé: “Ààlà ilẹ̀ àwọn arákùnrin yín, àwọn àtọmọdọ́mọ Ísọ̀,+ tí wọ́n ń gbé ní Séírì,+ lẹ máa gbà kọjá, ẹ̀rù yín á sì máa bà wọ́n,+ torí náà, ẹ ṣọ́ra gidigidi. Diutarónómì 23:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 “O ò gbọ́dọ̀ kórìíra ọmọ Édómù, torí arákùnrin rẹ ni.+ “O ò gbọ́dọ̀ kórìíra ọmọ Íjíbítì, torí o di àjèjì ní ilẹ̀ rẹ̀.+
4 Kí o sì pàṣẹ fún àwọn èèyàn náà pé: “Ààlà ilẹ̀ àwọn arákùnrin yín, àwọn àtọmọdọ́mọ Ísọ̀,+ tí wọ́n ń gbé ní Séírì,+ lẹ máa gbà kọjá, ẹ̀rù yín á sì máa bà wọ́n,+ torí náà, ẹ ṣọ́ra gidigidi.
7 “O ò gbọ́dọ̀ kórìíra ọmọ Édómù, torí arákùnrin rẹ ni.+ “O ò gbọ́dọ̀ kórìíra ọmọ Íjíbítì, torí o di àjèjì ní ilẹ̀ rẹ̀.+