Nọ́ńbà 20:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Mósè wá ní kí àwọn ìránṣẹ́ lọ láti Kádéṣì sọ́dọ̀ ọba Édómù+ pé: “Ohun tí Ísírẹ́lì+ arákùnrin rẹ sọ nìyí, ‘Gbogbo ìpọ́njú tó dé bá wa ni ìwọ náà mọ̀ dáadáa. Diutarónómì 23:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 “O ò gbọ́dọ̀ kórìíra ọmọ Édómù, torí arákùnrin rẹ ni.+ “O ò gbọ́dọ̀ kórìíra ọmọ Íjíbítì, torí o di àjèjì ní ilẹ̀ rẹ̀.+
14 Mósè wá ní kí àwọn ìránṣẹ́ lọ láti Kádéṣì sọ́dọ̀ ọba Édómù+ pé: “Ohun tí Ísírẹ́lì+ arákùnrin rẹ sọ nìyí, ‘Gbogbo ìpọ́njú tó dé bá wa ni ìwọ náà mọ̀ dáadáa.
7 “O ò gbọ́dọ̀ kórìíra ọmọ Édómù, torí arákùnrin rẹ ni.+ “O ò gbọ́dọ̀ kórìíra ọmọ Íjíbítì, torí o di àjèjì ní ilẹ̀ rẹ̀.+