28“Kí o mú Áárónì ẹ̀gbọ́n rẹ, pẹ̀lú àwọn ọmọ rẹ̀ látinú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, kí wọ́n lè di àlùfáà mi,+ Áárónì,+ pẹ̀lú Nádábù àti Ábíhù,+ Élíásárì àti Ítámárì,+ àwọn ọmọ Áárónì.+
2 “Mú Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀+ pẹ̀lú àwọn aṣọ,+ òróró àfiyanni,+ akọ màlúù ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀, àgbò méjì àti apẹ̀rẹ̀ búrẹ́dì aláìwú,+3 kí o sì mú kí gbogbo àpéjọ náà kóra jọ sí ẹnu ọ̀nà àgọ́ ìpàdé.”