ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Nọ́ńbà 10:12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì bẹ̀rẹ̀ sí í kúrò ní aginjù Sínáì, wọ́n tẹ̀ lé ètò tó wà nílẹ̀ nípa bí wọ́n ṣe máa gbéra,+ ìkùukùu náà sì dúró ní aginjù Páránì.+

  • Diutarónómì 8:14, 15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 má ṣe gbéra ga nínú ọkàn rẹ,+ kó sì mú kí o gbàgbé Jèhófà Ọlọ́run rẹ tó mú ọ kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì, kúrò ní ilé ẹrú,+ 15 ẹni tó mú ọ rin inú aginjù tí ó tóbi tó sì ń bani lẹ́rù,+ tó ní àwọn ejò olóró àti àwọn àkekèé, tí ilẹ̀ ibẹ̀ gbẹ tí kò sì lómi. Ó mú kí omi ṣàn jáde látinú akọ àpáta,+

  • Jeremáyà 2:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  6 Wọn kò béèrè pé, ‘Ibo ni Jèhófà wà,

      Ẹni tó mú wa jáde kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì,+

      Tó mú wa gba aginjù kọjá,

      Tó mú wa gba aṣálẹ̀+ àti kòtò kọjá,

      Tó mú wa gba ilẹ̀ aláìlómi + àti ilẹ̀ òkùnkùn biribiri kọjá,

      Tó mú wa gba ilẹ̀ tí èèyàn kì í gbà kọjá,

      Ilẹ̀ tí èèyàn kì í gbé?’

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́