ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 19:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 19 Ní ọjọ́ tó pé oṣù mẹ́ta tí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì, wọ́n dé aginjù Sínáì.

  • Nọ́ńbà 10:11, 12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Ó ṣẹlẹ̀ pé ní ogúnjọ́ oṣù kejì, ọdún kejì,+ ìkùukùu* náà gbéra lórí àgọ́+ Ẹ̀rí. 12 Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì bẹ̀rẹ̀ sí í kúrò ní aginjù Sínáì, wọ́n tẹ̀ lé ètò tó wà nílẹ̀ nípa bí wọ́n ṣe máa gbéra,+ ìkùukùu náà sì dúró ní aginjù Páránì.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́