Diutarónómì 30:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Jèhófà Ọlọ́run rẹ máa bù kún gbogbo iṣẹ́ ọwọ́+ rẹ lọ́pọ̀lọpọ̀, ó máa mú kí àwọn ọmọ rẹ, àwọn ẹran ọ̀sìn rẹ àti èso ilẹ̀ rẹ di púpọ̀, torí pé lẹ́ẹ̀kan sí i inú Jèhófà máa dùn láti mú kí nǹkan lọ dáadáa fún ọ bí inú rẹ̀ ṣe dùn sí àwọn baba ńlá+ rẹ. Sáàmù 65:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ò ń bójú tó ayé,O mú kí ó ní ọ̀pọ̀ rẹpẹtẹ èso,* kí ilẹ̀ rẹ̀ sì lọ́ràá dáadáa.+ Omi kún inú odò Ọlọ́run;O pèsè oúnjẹ* fún wọn,+Nítorí bí o ṣe ṣètò ayé nìyẹn.
9 Jèhófà Ọlọ́run rẹ máa bù kún gbogbo iṣẹ́ ọwọ́+ rẹ lọ́pọ̀lọpọ̀, ó máa mú kí àwọn ọmọ rẹ, àwọn ẹran ọ̀sìn rẹ àti èso ilẹ̀ rẹ di púpọ̀, torí pé lẹ́ẹ̀kan sí i inú Jèhófà máa dùn láti mú kí nǹkan lọ dáadáa fún ọ bí inú rẹ̀ ṣe dùn sí àwọn baba ńlá+ rẹ.
9 Ò ń bójú tó ayé,O mú kí ó ní ọ̀pọ̀ rẹpẹtẹ èso,* kí ilẹ̀ rẹ̀ sì lọ́ràá dáadáa.+ Omi kún inú odò Ọlọ́run;O pèsè oúnjẹ* fún wọn,+Nítorí bí o ṣe ṣètò ayé nìyẹn.