ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jẹ́nẹ́sísì 49:22
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 22 “Jósẹ́fù+ jẹ́ èéhù igi eléso, igi tó ń so lẹ́bàá ìsun omi, tí àwọn ẹ̀ka rẹ̀ nà sórí ògiri.

  • Jẹ́nẹ́sísì 49:24
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 24 Síbẹ̀, ọfà* rẹ̀ dúró sí àyè rẹ̀,+ ọwọ́ rẹ̀ lágbára, ó sì já fáfá.+ Èyí wá láti ọwọ́ alágbára Jékọ́bù, láti ọwọ́ olùṣọ́ àgùntàn, òkúta Ísírẹ́lì.

  • Jóṣúà 16:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 Ilẹ̀ tí wọ́n fi kèké pín*+ fún àwọn àtọmọdọ́mọ Jósẹ́fù+ bẹ̀rẹ̀ láti Jọ́dánì ní Jẹ́ríkò dé ibi omi tó wà lápá ìlà oòrùn Jẹ́ríkò, ó gba inú aginjù láti Jẹ́ríkò lọ sí agbègbè olókè Bẹ́tẹ́lì.+

  • Sáàmù 44:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  3 Kì í ṣe idà wọn ni wọ́n fi gba ilẹ̀ náà,+

      Kì í sì í ṣe apá wọn ló mú kí wọ́n ṣẹ́gun.+

      Kàkà bẹ́ẹ̀, ọwọ́ ọ̀tún rẹ àti apá rẹ+ àti ìmọ́lẹ̀ ojú rẹ ló ṣe é,

      Nítorí pé inú rẹ dùn sí wọn.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́