Àwọn Onídàájọ́ 17:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ọ̀dọ́kùnrin kan wà tó jẹ́ ará Bẹ́tílẹ́hẹ́mù+ ní Júdà, látinú ìdílé Júdà. Ọmọ Léfì+ ni, ó sì ti ń gbé níbẹ̀ fúngbà díẹ̀. Àwọn Onídàájọ́ 17:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Yàtọ̀ síyẹn, Míkà fiṣẹ́ lé ọmọ Léfì náà lọ́wọ́* pé kó di àlùfáà rẹ̀,+ ó sì ń gbé ní ilé Míkà. Àwọn Onídàájọ́ 18:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Lẹ́yìn náà, àwọn ọmọ Dánì gbé ère gbígbẹ́ náà+ kalẹ̀ fún ara wọn, Jónátánì+ ọmọ Gẹ́ṣómù,+ ọmọ Mósè àti àwọn ọmọkùnrin rẹ̀ sì di àlùfáà fún ẹ̀yà àwọn ọmọ Dánì títí di ọjọ́ tí àwọn tó ń gbé ilẹ̀ náà fi lọ sí ìgbèkùn.
7 Ọ̀dọ́kùnrin kan wà tó jẹ́ ará Bẹ́tílẹ́hẹ́mù+ ní Júdà, látinú ìdílé Júdà. Ọmọ Léfì+ ni, ó sì ti ń gbé níbẹ̀ fúngbà díẹ̀.
30 Lẹ́yìn náà, àwọn ọmọ Dánì gbé ère gbígbẹ́ náà+ kalẹ̀ fún ara wọn, Jónátánì+ ọmọ Gẹ́ṣómù,+ ọmọ Mósè àti àwọn ọmọkùnrin rẹ̀ sì di àlùfáà fún ẹ̀yà àwọn ọmọ Dánì títí di ọjọ́ tí àwọn tó ń gbé ilẹ̀ náà fi lọ sí ìgbèkùn.