ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Léfítíkù 19:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 Ẹ má ṣe yíjú sí àwọn ọlọ́run tí kò ní láárí+ tàbí kí ẹ fi irin rọ àwọn ọlọ́run+ fún ara yín. Èmi ni Jèhófà Ọlọ́run yín.

  • Diutarónómì 27:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 “‘Ègún ni fún ẹni tó bá gbẹ́ ère+ tàbí tó ṣe ère onírin,*+ tó jẹ́ ohun ìríra lójú Jèhófà,+ iṣẹ́ ọwọ́ oníṣẹ́ ọnà,* tó sì gbé e pa mọ́.’ (Kí gbogbo èèyàn sì sọ pé, ‘Àmín!’*)

  • Àwọn Onídàájọ́ 17:3-5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Ó wá kó ẹgbẹ̀rún kan ó lé ọgọ́rùn-ún (1,100) ẹyọ fàdákà náà pa dà fún ìyá rẹ̀, àmọ́ ìyá rẹ̀ sọ pé: “Ó dájú pé màá ya fàdákà náà sí mímọ́ fún Jèhófà látọwọ́ mi, kí ọmọ mi lè fi ṣe ère gbígbẹ́ àti ère onírin.*+ Mo fún ọ pa dà báyìí.”

      4 Lẹ́yìn tó dá fàdákà náà pa dà fún ìyá rẹ̀, ìyá rẹ̀ mú igba (200) ẹyọ fàdákà, ó sì fún alágbẹ̀dẹ fàdákà. Ó ṣe ère gbígbẹ́ àti ère onírin;* wọ́n sì gbé e sínú ilé Míkà. 5 Ọkùnrin tó ń jẹ́ Míkà yìí ní ilé kan tó kó àwọn ọlọ́run rẹ̀ sí, ó ṣe éfódì kan+ àti àwọn ère tẹ́ráfímù,*+ ó sì yan* ọ̀kan nínú àwọn ọmọ rẹ̀ pé kó jẹ́ àlùfáà rẹ̀.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́