4 Kí ààlà yín sì yí gba gúúsù, kó gba ibi tí wọ́n ń gbà gòkè ní Ákírábímù+ títí lọ dé Síínì, kó sì parí sí gúúsù Kadeṣi-báníà.+ Kó wá dé Hasari-ádáárì+ títí lọ dé Ásímónì.
3 Ó sì lọ sápá gúúsù dé ibi tí wọ́n ń gbà gòkè ní Ákírábímù,+ ó dé Síínì, ó gba gúúsù lọ sí Kadeṣi-báníà,+ ó dé Hésírónì, lọ dé Ádáárì, ó sì yí gba ọ̀nà Káríkà.