-
1 Kíróníkà 2:9-15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Àwọn ọmọ Hésírónì ni Jéráméélì,+ Rámù+ àti Kélúbáì.*
10 Rámù bí Ámínádábù. Ámínádábù+ bí Náṣónì,+ ìjòyè àwọn ọmọ Júdà. 11 Náṣónì bí Sálímà.+ Sálímà bí Bóásì.+ 12 Bóásì bí Óbédì. Óbédì bí Jésè.+ 13 Jésè bí àkọ́bí rẹ̀ Élíábù, ìkejì Ábínádábù,+ ìkẹta Ṣíméà,+ 14 ìkẹrin Nétánélì, ìkarùn-ún Rádáì, 15 ìkẹfà Ósémù àti ìkeje Dáfídì.+
-