Sáàmù 3:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Dìde, Jèhófà! Gbà mí sílẹ̀,+ ìwọ Ọlọ́run mi! Nítorí wàá gbá gbogbo àwọn ọ̀tá mi ní páárì ẹ̀rẹ̀kẹ́;Wàá ká eyín àwọn ẹni burúkú.+ Sáàmù 56:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Àwọn ọ̀tá mi á sá pa dà ní ọjọ́ tí mo bá ké pè ọ́ fún ìrànlọ́wọ́.+ Ó dá mi lójú pé: Ọlọ́run wà pẹ̀lú mi.+
7 Dìde, Jèhófà! Gbà mí sílẹ̀,+ ìwọ Ọlọ́run mi! Nítorí wàá gbá gbogbo àwọn ọ̀tá mi ní páárì ẹ̀rẹ̀kẹ́;Wàá ká eyín àwọn ẹni burúkú.+
9 Àwọn ọ̀tá mi á sá pa dà ní ọjọ́ tí mo bá ké pè ọ́ fún ìrànlọ́wọ́.+ Ó dá mi lójú pé: Ọlọ́run wà pẹ̀lú mi.+