ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 78:38
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 38 Àmọ́, ó jẹ́ aláàánú;+

      Ó máa ń dárí ẹ̀ṣẹ̀ wọn jì wọ́n,* kò sì ní pa wọ́n run.+

      Ó máa ń fawọ́ ìbínú rẹ̀ sẹ́yìn lọ́pọ̀ ìgbà,+

      Kàkà tí ì bá fi jẹ́ kí gbogbo ìbínú rẹ̀ ru.

  • Jeremáyà 26:19
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 19 “Ṣé Ọba Hẹsikáyà ti Júdà àti gbogbo àwọn èèyàn Júdà wá pa á ni? Ǹjẹ́ kò bẹ̀rù Jèhófà, tó sì bẹ Jèhófà pé kó ṣojú rere sí òun,* tí Jèhófà fi pèrò dà* lórí àjálù tó sọ pé òun máa mú bá wọn?+ Nítorí náà, àjálù ńlá ni a fẹ́ fà wá bá ara* wa yìí o.

  • Jóẹ́lì 2:13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Ọkàn yín ni kí ẹ fà ya,+ kì í ṣe ẹ̀wù yín,+

      Kí ẹ sì pa dà sọ́dọ̀ Jèhófà Ọlọ́run yín,

      Torí ó ń gba tẹni rò,* ó jẹ́ aláàánú, kì í tètè bínú,+ ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ sì pọ̀ gidigidi,+

      Òun yóò sì pèrò dà* nípa àjálù náà.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́