ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Àwọn Ọba 20:17
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 ‘Wò ó! Ọjọ́ ń bọ̀ tí wọ́n máa kó gbogbo ohun tó wà nínú ilé* rẹ àti gbogbo ohun tí àwọn baba ńlá rẹ ti kó jọ títí di òní yìí lọ sí Bábílónì.+ Kò ní ku nǹkan kan,’ ni Jèhófà wí.

  • Jeremáyà 52:17-20
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 Àwọn ará Kálídíà fọ́ àwọn òpó bàbà+ ilé Jèhófà àti àwọn kẹ̀kẹ́ ẹrù + àti Òkun bàbà+ tó wà ní ilé Jèhófà sí wẹ́wẹ́, wọ́n sì kó gbogbo bàbà náà lọ sí Bábílónì.+ 18 Wọ́n tún kó àwọn garawa, àwọn ṣọ́bìrì, àwọn ohun tí wọ́n fi ń pa fìtílà, àwọn abọ́,+ àwọn ife+ àti gbogbo nǹkan èlò bàbà tí wọ́n ń lò nínú tẹ́ńpìlì. 19 Olórí ẹ̀ṣọ́ kó àwọn bàsíà,+ àwọn ìkóná, àwọn abọ́, àwọn garawa, àwọn ọ̀pá fìtílà,+ àwọn ife àti àwọn abọ́ tí wọ́n fi ojúlówó wúrà ṣe àti àwọn tí wọ́n fi ojúlówó fàdákà ṣe.+ 20 Ní ti àwọn òpó méjèèjì àti Òkun, àwọn akọ màlúù méjìlá (12)+ tí wọ́n fi bàbà ṣe tó wà lábẹ́ Òkun náà àti àwọn kẹ̀kẹ́ ẹrù tí Ọba Sólómọ́nì ṣe fún ilé Jèhófà, bàbà tó wà lára gbogbo àwọn nǹkan èlò yìí kọjá wíwọ̀n.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́