ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Àwọn Ọba 17:19, 20
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 19 Àmọ́, ó sọ fún un pé: “Gbé ọmọ rẹ fún mi.” Nígbà náà, ó gbà á lọ́wọ́ rẹ̀, ó gbé e lọ sí yàrá orí òrùlé, níbi tó ń gbé, ó sì tẹ́ ẹ sórí ibùsùn rẹ̀.+ 20 Ó ké pe Jèhófà pé: “Jèhófà Ọlọ́run mi,+ ṣé wàá tún mú àjálù bá opó tí mò ń gbé lọ́dọ̀ rẹ̀ ni, tí o fi jẹ́ kí ọmọ rẹ̀ kú?”

  • Jòhánù 11:41
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 41 Torí náà, wọ́n gbé òkúta náà kúrò. Jésù wá gbójú sókè wo ọ̀run,+ ó sì sọ pé: “Baba, mo dúpẹ́ lọ́wọ́ rẹ pé o ti gbọ́ tèmi.

  • Ìṣe 9:40
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 40 Pétérù wá ní kí gbogbo èèyàn bọ́ síta,+ ó kúnlẹ̀, ó sì gbàdúrà. Lẹ́yìn náà, ó yíjú sí òkú náà, ó sọ pé: “Tàbítà, dìde!” Obìnrin náà lajú, bó ṣe tajú kán rí Pétérù, ó dìde jókòó.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́