Nọ́ńbà 1:50 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 50 Kí o yan àwọn ọmọ Léfì láti máa bójú tó àgọ́ Ẹ̀rí+ àti gbogbo ohun èlò rẹ̀ pẹ̀lú gbogbo ohun tó jẹ́ ti àgọ́ náà.+ Kí wọ́n máa gbé àgọ́ ìjọsìn náà àti gbogbo ohun èlò rẹ̀,+ kí wọ́n máa ṣiṣẹ́ níbẹ̀,+ kí wọ́n sì pàgọ́ yí àgọ́ ìjọsìn+ náà ká.
50 Kí o yan àwọn ọmọ Léfì láti máa bójú tó àgọ́ Ẹ̀rí+ àti gbogbo ohun èlò rẹ̀ pẹ̀lú gbogbo ohun tó jẹ́ ti àgọ́ náà.+ Kí wọ́n máa gbé àgọ́ ìjọsìn náà àti gbogbo ohun èlò rẹ̀,+ kí wọ́n máa ṣiṣẹ́ níbẹ̀,+ kí wọ́n sì pàgọ́ yí àgọ́ ìjọsìn+ náà ká.