-
1 Àwọn Ọba 7:47Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
47 Sólómọ́nì fi gbogbo nǹkan èlò náà sílẹ̀ láìwọ̀n wọ́n nítorí wọ́n ti pọ̀ jù. A kò mọ bí ìwọ̀n bàbà náà ṣe pọ̀ tó.+
-
-
Jeremáyà 52:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 Ní ti àwọn òpó méjèèjì àti Òkun, àwọn akọ màlúù méjìlá (12)+ tí wọ́n fi bàbà ṣe tó wà lábẹ́ Òkun náà àti àwọn kẹ̀kẹ́ ẹrù tí Ọba Sólómọ́nì ṣe fún ilé Jèhófà, bàbà tó wà lára gbogbo àwọn nǹkan èlò yìí kọjá wíwọ̀n.
-