Nọ́ńbà 34:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 “Fi ìtọ́ni yìí tó àwọn ọmọ Ísírẹ́lì létí pé, ‘Tí ẹ bá wọ ilẹ̀ Kénáánì,+ ilẹ̀ tó máa di tiyín nìyí láwọn ibi tí ààlà+ rẹ̀ dé. Nọ́ńbà 34:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Kí ààlà náà yí gba Àfonífojì Íjíbítì láti Ásímónì, kó sì parí sí Òkun.*+ Nọ́ńbà 34:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Kí ẹ pààlà yín láti Òkè Hóórì dé Lebo-hámátì,*+ kí ààlà náà sì parí sí Sédádì.+
2 “Fi ìtọ́ni yìí tó àwọn ọmọ Ísírẹ́lì létí pé, ‘Tí ẹ bá wọ ilẹ̀ Kénáánì,+ ilẹ̀ tó máa di tiyín nìyí láwọn ibi tí ààlà+ rẹ̀ dé.