Sáàmù 106:43, 44 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 43 Ọ̀pọ̀ ìgbà ló gbà wọ́n sílẹ̀,+Àmọ́ wọ́n á ṣọ̀tẹ̀, wọ́n á sì ṣàìgbọràn,+A ó sì rẹ̀ wọ́n sílẹ̀ nítorí àṣìṣe wọn.+ 44 Àmọ́ á tún rí ìdààmú tó bá wọn,+Á sì gbọ́ igbe ìrànlọ́wọ́ wọn.+ Àìsáyà 55:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Kí èèyàn burúkú fi ọ̀nà rẹ̀ sílẹ̀,+Kí ẹni ibi sì yí èrò rẹ̀ pa dà;Kó pa dà sọ́dọ̀ Jèhófà, ẹni tó máa ṣàánú rẹ̀,+Sọ́dọ̀ Ọlọ́run wa, torí ó máa dárí jini fàlàlà.*+
43 Ọ̀pọ̀ ìgbà ló gbà wọ́n sílẹ̀,+Àmọ́ wọ́n á ṣọ̀tẹ̀, wọ́n á sì ṣàìgbọràn,+A ó sì rẹ̀ wọ́n sílẹ̀ nítorí àṣìṣe wọn.+ 44 Àmọ́ á tún rí ìdààmú tó bá wọn,+Á sì gbọ́ igbe ìrànlọ́wọ́ wọn.+
7 Kí èèyàn burúkú fi ọ̀nà rẹ̀ sílẹ̀,+Kí ẹni ibi sì yí èrò rẹ̀ pa dà;Kó pa dà sọ́dọ̀ Jèhófà, ẹni tó máa ṣàánú rẹ̀,+Sọ́dọ̀ Ọlọ́run wa, torí ó máa dárí jini fàlàlà.*+