Léfítíkù 6:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Kí àlùfáà wọ ẹ̀wù oyè rẹ̀ tí wọ́n fi aṣọ ọ̀gbọ̀*+ ṣe, kó sì wọ ṣòkòtò péńpé*+ láti bo ara rẹ̀. Kó wá kó eérú*+ ẹbọ sísun tí wọ́n ti fi iná jó lórí pẹpẹ kúrò, kó sì kó o sẹ́gbẹ̀ẹ́ pẹpẹ.
10 Kí àlùfáà wọ ẹ̀wù oyè rẹ̀ tí wọ́n fi aṣọ ọ̀gbọ̀*+ ṣe, kó sì wọ ṣòkòtò péńpé*+ láti bo ara rẹ̀. Kó wá kó eérú*+ ẹbọ sísun tí wọ́n ti fi iná jó lórí pẹpẹ kúrò, kó sì kó o sẹ́gbẹ̀ẹ́ pẹpẹ.