ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jóòbù 16:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  9 Ìbínú rẹ̀ ti fà mí ya pẹ́rẹpẹ̀rẹ, ó sì ń dì mí sínú.+

      Ó ń wa eyín pọ̀ sí mi.

      Ọ̀tá mi ń fi ojú rẹ̀ gún mi lára.+

  • Jóòbù 19:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Ó bínú sí mi gidigidi,

      Ó sì kà mí sí ọ̀tá rẹ̀.+

  • Jóòbù 33:8-11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  8 Àmọ́, o sọ ọ́ létí mi,

      Àní mo ṣáà ń gbọ́ tí ò ń sọ pé,

       9 ‘Mo mọ́, mi ò ní ẹ̀ṣẹ̀ lọ́rùn;+

      Mo mọ́, mi ò ní àṣìṣe.+

      10 Àmọ́ Ọlọ́run rí ìdí tó fi yẹ kó ta kò mí;

      Ó kà mí sí ọ̀tá rẹ̀.+

      11 Ó ti ẹsẹ̀ mi mọ́ inú àbà;

      Ó ń ṣọ́ gbogbo ọ̀nà mi lójú méjèèjì.’+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́