Sáàmù 58:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Nígbà náà, aráyé á sọ pé: “Dájúdájú, èrè wà fún olódodo.+ Ní tòótọ́, Ọlọ́run kan wà tó ń ṣe ìdájọ́ ayé.”+ Mátíù 7:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 “Ẹ yéé dáni lẹ́jọ́,+ kí a má bàa dá yín lẹ́jọ́; Róòmù 14:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ta ni ọ́, tí o fi ń ṣèdájọ́ ìránṣẹ́ ẹlòmíì?+ Ọ̀gá rẹ̀ ló máa pinnu bóyá ó máa ṣubú tàbí ó máa wà ní ìdúró.+ Ní tòótọ́, a máa mú un dúró, nítorí Jèhófà* lè mú un dúró. Jémíìsì 4:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ẹnì kan ṣoṣo ni Afúnnilófin àti Onídàájọ́ wa,+ ẹni tó lè gbà là, tó sì lè pa run.+ Àmọ́ ìwọ, ta ni ọ́ tí o fi ń dá ọmọnìkejì rẹ lẹ́jọ́?+
11 Nígbà náà, aráyé á sọ pé: “Dájúdájú, èrè wà fún olódodo.+ Ní tòótọ́, Ọlọ́run kan wà tó ń ṣe ìdájọ́ ayé.”+
4 Ta ni ọ́, tí o fi ń ṣèdájọ́ ìránṣẹ́ ẹlòmíì?+ Ọ̀gá rẹ̀ ló máa pinnu bóyá ó máa ṣubú tàbí ó máa wà ní ìdúró.+ Ní tòótọ́, a máa mú un dúró, nítorí Jèhófà* lè mú un dúró.
12 Ẹnì kan ṣoṣo ni Afúnnilófin àti Onídàájọ́ wa,+ ẹni tó lè gbà là, tó sì lè pa run.+ Àmọ́ ìwọ, ta ni ọ́ tí o fi ń dá ọmọnìkejì rẹ lẹ́jọ́?+