Sáàmù 11:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Jèhófà wà nínú tẹ́ńpìlì mímọ́ rẹ̀.+ Ìtẹ́ Jèhófà wà ní ọ̀run.+ Ojú rẹ̀ ń wò, ojú rẹ̀ tó rí ohun gbogbo* ń ṣàyẹ̀wò àwọn ọmọ èèyàn.+ Òwe 5:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Nítorí àwọn ọ̀nà èèyàn wà níwájú Jèhófà;Ó ń ṣàyẹ̀wò gbogbo ipa ọ̀nà rẹ̀.+ Òwe 15:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ojú Jèhófà wà níbi gbogbo,Ó ń ṣọ́ ẹni burúkú àti ẹni rere.+
4 Jèhófà wà nínú tẹ́ńpìlì mímọ́ rẹ̀.+ Ìtẹ́ Jèhófà wà ní ọ̀run.+ Ojú rẹ̀ ń wò, ojú rẹ̀ tó rí ohun gbogbo* ń ṣàyẹ̀wò àwọn ọmọ èèyàn.+