2 Àwọn Ọba 20:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Ní ti ìyókù ìtàn Hẹsikáyà àti gbogbo agbára rẹ̀ àti bí ó ṣe ṣe adágún odò+ àti ọ̀nà omi àti bí ó ṣe gbé omi wá sínú ìlú,+ ǹjẹ́ kò wà lákọsílẹ̀ nínú ìwé ìtàn ìgbà àwọn ọba Júdà? 2 Kíróníkà 32:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Hẹsikáyà ló dí orísun omi+ Gíhónì+ tó wà lápá òkè pa, ó sì darí rẹ̀ tààràtà lọ sí ìwọ̀ oòrùn Ìlú Dáfídì.+ Hẹsikáyà ṣàṣeyọrí nínú gbogbo iṣẹ́ rẹ̀.
20 Ní ti ìyókù ìtàn Hẹsikáyà àti gbogbo agbára rẹ̀ àti bí ó ṣe ṣe adágún odò+ àti ọ̀nà omi àti bí ó ṣe gbé omi wá sínú ìlú,+ ǹjẹ́ kò wà lákọsílẹ̀ nínú ìwé ìtàn ìgbà àwọn ọba Júdà?
30 Hẹsikáyà ló dí orísun omi+ Gíhónì+ tó wà lápá òkè pa, ó sì darí rẹ̀ tààràtà lọ sí ìwọ̀ oòrùn Ìlú Dáfídì.+ Hẹsikáyà ṣàṣeyọrí nínú gbogbo iṣẹ́ rẹ̀.