-
Léfítíkù 19:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 “‘Ẹ ò gbọ́dọ̀ yí ìdájọ́ po. Ẹ ò gbọ́dọ̀ rẹ́ aláìní jẹ tàbí kí ẹ ṣe ojúsàájú sí ọlọ́rọ̀.+ Máa ṣe ìdájọ́ òdodo tí o bá ń dá ẹjọ́ ẹnì kejì rẹ.
-
-
Òwe 24:23Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
23 Ọ̀rọ̀ wọ̀nyí tún jẹ́ ti àwọn ọlọ́gbọ́n:
Kò dára láti máa ṣe ojúsàájú nínú ìdájọ́.+
-