ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Diutarónómì 34:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 Ẹni ọgọ́fà (120) ọdún ni Mósè nígbà tó kú.+ Ojú rẹ̀ ò di bàìbàì, agbára rẹ̀ ò sì dín kù.

  • Jóòbù 42:16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 Lẹ́yìn èyí, Jóòbù lo ogóje (140) ọdún sí i láyé, ó sì rí àwọn ọmọ rẹ̀ àti àwọn ọmọ ọmọ rẹ̀, dé ìran kẹrin.

  • Sáàmù 103:3-5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  3 Ó ń dárí gbogbo àṣìṣe mi jì mí,+

      Ó sì ń wo gbogbo àìsàn mi sàn;+

       4 Ó gba ẹ̀mí mi pa dà látinú kòtò,*+

      Ó sì fi ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ àti àánú dé mi ládé,+

       5 Ó ń fi ohun rere tẹ́ mi lọ́rùn+ ní gbogbo ọjọ́ ayé mi,

      Kí agbára* mi lè di ọ̀tun bíi ti ẹyẹ idì.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́