ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Nọ́ńbà 11:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Mósè wá sọ fún Jèhófà pé: “Kí ló dé tí o fìyà jẹ ìránṣẹ́ rẹ? Kí ló dé tí o kò ṣojúure sí mi, tí o sì di ẹrù gbogbo àwọn èèyàn yìí lé mi lórí?+

  • Nọ́ńbà 11:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Tó bá jẹ́ ohun tí o fẹ́ ṣe fún mi nìyí, jọ̀ọ́ kúkú pa mí báyìí.+ Tí mo bá rí ojúure rẹ, má ṣe jẹ́ kí ojú mi tún rí ibi mọ́.”

  • 1 Àwọn Ọba 19:3, 4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Ẹ̀rù wá bẹ̀rẹ̀ sí í bà á, torí náà, ó gbéra, ó sì sá nítorí ẹ̀mí* rẹ̀.+ Ó wá sí Bíá-ṣébà+ tó jẹ́ ti Júdà,+ ó sì fi ìránṣẹ́ rẹ̀ sílẹ̀ níbẹ̀. 4 Ó rin ìrìn ọjọ́ kan lọ sínú aginjù, ó dúró, ó jókòó sábẹ́ igi wíwẹ́, ó sì béèrè pé kí òun* kú. Ó sọ pé: “Ó tó gẹ́ẹ́! Jèhófà, gba ẹ̀mí* mi,+ nítorí mi ò sàn ju àwọn baba ńlá mi.”

  • Jónà 4:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Jèhófà, jọ̀ọ́ gbẹ̀mí* mi, torí ó sàn kí n kú ju kí n wà láàyè.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́