Sáàmù 104:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ó tẹ́ igi àjà àwọn yàrá òkè rẹ̀ sínú omi lókè,*+Ó fi àwọsánmà ṣe kẹ̀kẹ́ ẹṣin rẹ̀,+Ó ń lọ lórí ìyẹ́ apá ẹ̀fúùfù.+
3 Ó tẹ́ igi àjà àwọn yàrá òkè rẹ̀ sínú omi lókè,*+Ó fi àwọsánmà ṣe kẹ̀kẹ́ ẹṣin rẹ̀,+Ó ń lọ lórí ìyẹ́ apá ẹ̀fúùfù.+