Sáàmù 104:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ó ń bomi rin àwọn òkè láti àwọn yàrá òkè rẹ̀.+ Iṣẹ́ ọwọ́* rẹ ń tẹ́ ilẹ̀ ayé lọ́rùn.+ Sáàmù 107:35 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 35 Ó ń sọ aṣálẹ̀ di adágún omi tí esùsú* kún inú rẹ̀,Ó sì ń sọ ilẹ̀ gbígbẹ di ìṣàn omi.+