ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Sámúẹ́lì 4:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 Àmọ́, Dáfídì dá Rékábù àti Báánà arákùnrin rẹ̀, àwọn ọmọ Rímónì ará Béérótì lóhùn pé: “Bí Jèhófà ẹni tí ó yọ mí* nínú gbogbo wàhálà+ ti wà láàyè,

  • Sáàmù 34:19
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 19 Ìṣòro* olódodo máa ń pọ̀,+

      Àmọ́ Jèhófà ń gbà á sílẹ̀ nínú gbogbo rẹ̀.+

  • Sáàmù 37:39
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 39 Ọ̀dọ̀ Jèhófà ni ìgbàlà àwọn olódodo ti wá;+

      Òun ni odi ààbò wọn ní àkókò wàhálà.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́