Sáàmù 140:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Wọ́n pọ́n ahọ́n wọn bíi ti ejò;+Oró paramọ́lẹ̀ wà lábẹ́ ètè wọn.+ (Sélà) Jémíìsì 3:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Àmọ́ kò sí èèyàn tó lè kápá ahọ́n. Aláìgbọràn ni, ó sì ń ṣeni léṣe, ó kún fún májèlé tó ń pani.+