Sáàmù 52:1, 2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 52 Kí ló dé tí ò ń fi ìwà burúkú rẹ ṣògo, ìwọ alágbára ńlá?+ Ṣé o kò mọ̀ pé ìfẹ́ Ọlọ́run tí kì í yẹ̀ wà láti ọjọ́ dé ọjọ́ ni?+ 2 Ahọ́n rẹ mú bí abẹ fẹ́lẹ́,+Ó ń pète ibi, ó sì ń ṣiṣẹ́ ẹ̀tàn.+ Sáàmù 58:3, 4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Àwọn ẹni burúkú ti ṣìnà* látìgbà tí wọ́n ti bí wọn;*Oníwàkiwà ni wọ́n, òpùrọ́ sì ni wọ́n látìgbà tí wọ́n ti bí wọn. 4 Oró wọ́n dà bí oró ejò;+Wọ́n jẹ́ adití bí ejò ṣèbé tó di etí rẹ̀.
52 Kí ló dé tí ò ń fi ìwà burúkú rẹ ṣògo, ìwọ alágbára ńlá?+ Ṣé o kò mọ̀ pé ìfẹ́ Ọlọ́run tí kì í yẹ̀ wà láti ọjọ́ dé ọjọ́ ni?+ 2 Ahọ́n rẹ mú bí abẹ fẹ́lẹ́,+Ó ń pète ibi, ó sì ń ṣiṣẹ́ ẹ̀tàn.+
3 Àwọn ẹni burúkú ti ṣìnà* látìgbà tí wọ́n ti bí wọn;*Oníwàkiwà ni wọ́n, òpùrọ́ sì ni wọ́n látìgbà tí wọ́n ti bí wọn. 4 Oró wọ́n dà bí oró ejò;+Wọ́n jẹ́ adití bí ejò ṣèbé tó di etí rẹ̀.