Sáàmù 65:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 65 Ọlọ́run, ìyìn ń dúró dè ọ́ ní Síónì;+A ó san ẹ̀jẹ́ wa fún ọ.+ Sáàmù 66:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Màá mú odindi ẹbọ sísun wá sí ilé rẹ;+Màá san àwọn ẹ̀jẹ́ mi fún ọ+ Oníwàásù 5:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Nígbàkigbà tí o bá jẹ́ ẹ̀jẹ́ fún Ọlọ́run, má fi falẹ̀, san án,+ nítorí inú rẹ̀ kì í dùn sí àwọn òmùgọ̀.+ Ohun tí o jẹ́jẹ̀ẹ́, san án.+
4 Nígbàkigbà tí o bá jẹ́ ẹ̀jẹ́ fún Ọlọ́run, má fi falẹ̀, san án,+ nítorí inú rẹ̀ kì í dùn sí àwọn òmùgọ̀.+ Ohun tí o jẹ́jẹ̀ẹ́, san án.+