ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jẹ́nẹ́sísì 27:28
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 28 Kí Ọlọ́run tòótọ́ mú kí ìrì sẹ̀ fún ọ láti ọ̀run,+ kó fún ọ ní àwọn ilẹ̀ tó lọ́ràá ní ayé,+ kó sì fún ọ ní ọkà tó pọ̀ àti wáìnì tuntun.+

  • Diutarónómì 33:16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  16 Pẹ̀lú àwọn ohun tó dáa ní ayé àti ohun tó kún inú rẹ̀,+

      Kí Ẹni tó ń gbé inú igi ẹlẹ́gùn-ún+ sì tẹ́wọ́ gbà á.

      Kí wọ́n wá sí orí Jósẹ́fù,

      Sí àtàrí ẹni tí a yà sọ́tọ̀ lára àwọn arákùnrin rẹ̀.+

  • Málákì 3:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Ẹ mú gbogbo ìdá mẹ́wàá wá sínú ilé ìkẹ́rùsí,+ kí oúnjẹ lè wà nínú ilé mi.+ Ẹ jọ̀ọ́, ẹ fi èyí dán mi wò,” ni Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun wí, “kí ẹ lè rí i bóyá mi ò ní ṣí ibú omi ọ̀run,+ kí n sì tú* ìbùkún sórí yín títí ẹ kò fi ní ṣaláìní ohunkóhun.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́