Sáàmù 11:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Jèhófà wà nínú tẹ́ńpìlì mímọ́ rẹ̀.+ Ìtẹ́ Jèhófà wà ní ọ̀run.+ Ojú rẹ̀ ń wò, ojú rẹ̀ tó rí ohun gbogbo* ń ṣàyẹ̀wò àwọn ọmọ èèyàn.+ Òwe 15:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ojú Jèhófà wà níbi gbogbo,Ó ń ṣọ́ ẹni burúkú àti ẹni rere.+ Hébérù 4:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Kò sí ìṣẹ̀dá kankan tó fara pa mọ́ ní ojú rẹ̀,+ àmọ́ ohun gbogbo wà ní ìhòòhò, ó sì wà ní gbangba lójú ẹni tí a gbọ́dọ̀ jíhìn fún.+
4 Jèhófà wà nínú tẹ́ńpìlì mímọ́ rẹ̀.+ Ìtẹ́ Jèhófà wà ní ọ̀run.+ Ojú rẹ̀ ń wò, ojú rẹ̀ tó rí ohun gbogbo* ń ṣàyẹ̀wò àwọn ọmọ èèyàn.+
13 Kò sí ìṣẹ̀dá kankan tó fara pa mọ́ ní ojú rẹ̀,+ àmọ́ ohun gbogbo wà ní ìhòòhò, ó sì wà ní gbangba lójú ẹni tí a gbọ́dọ̀ jíhìn fún.+