ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jóòbù 27:8, 9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  8 Torí ìrètí wo ni ẹni tí kò mọ Ọlọ́run* ní tó bá pa run,+

      Tí Ọlọ́run bá gba ẹ̀mí* rẹ̀?

       9 Ṣé Ọlọ́run máa gbọ́ igbe rẹ̀,

      Tí wàhálà bá dé bá a?+

  • Òwe 15:29
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 29 Jèhófà jìnnà réré sí àwọn ẹni burúkú,

      Àmọ́ ó máa ń gbọ́ àdúrà àwọn olódodo.+

  • Òwe 28:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  9 Ẹni tí kì í fetí sí òfin,

      Àdúrà rẹ̀ pàápàá jẹ́ ohun ìríra.+

  • Àìsáyà 1:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Tí ẹ bá sì tẹ́ ọwọ́ yín,

      Mò ń fojú mi pa mọ́ fún yín.+

      Bí ẹ tiẹ̀ ń gbàdúrà púpọ̀,+

      Mi ò gbọ́ àdúrà yín;+

      Ẹ̀jẹ̀ kún ọwọ́ yín.+

  • Jòhánù 9:31
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 31 Àwa mọ̀ pé Ọlọ́run kì í tẹ́tí sí àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀,+ àmọ́ ẹnikẹ́ni tó bá ń bẹ̀rù Ọlọ́run, tó sì ń ṣe ìfẹ́ rẹ̀, ó máa ń tẹ́tí sí ẹni yìí.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́