Sáàmù 2:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Wàá fi ọ̀pá àṣẹ onírin+ ṣẹ́ wọn,Wàá sì fọ́ wọn túútúú bí ìkòkò amọ̀.”+ Sáàmù 110:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 110 Jèhófà sọ fún Olúwa mi pé: “Jókòó sí ọwọ́ ọ̀tún mi+Títí màá fi fi àwọn ọ̀tá rẹ ṣe àpótí ìtìsẹ̀ rẹ.”+
110 Jèhófà sọ fún Olúwa mi pé: “Jókòó sí ọwọ́ ọ̀tún mi+Títí màá fi fi àwọn ọ̀tá rẹ ṣe àpótí ìtìsẹ̀ rẹ.”+