Sáàmù 79:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 79 Ọlọ́run, àwọn orílẹ̀-èdè ti ya wọnú ogún rẹ;+Wọ́n ti sọ tẹ́ńpìlì mímọ́ rẹ di ẹlẹ́gbin;+Wọ́n ti sọ Jerúsálẹ́mù di àwókù.+
79 Ọlọ́run, àwọn orílẹ̀-èdè ti ya wọnú ogún rẹ;+Wọ́n ti sọ tẹ́ńpìlì mímọ́ rẹ di ẹlẹ́gbin;+Wọ́n ti sọ Jerúsálẹ́mù di àwókù.+